Mondadori Store

Trova Mondadori Store

Benvenuto
Accedi o registrati

lista preferiti

Per utilizzare la funzione prodotti desiderati devi accedere o registrarti

Vai al carrello
 prodotti nel carrello

Totale  articoli

0,00 € IVA Inclusa

Ádúrà Egberun-Odin-Laadota Ti O Bori Emi Adaniduro Ati Afi Ibukun Eni Si Abamo

Dr. Olusola Coker
pubblicato da Tektime

Prezzo online:
0,00

mi ágbé áwn ibùkún ni dè á máá dì nì lw àtí wnú àyànm l lásìkò, lòdì sí ákitiyán àtí ìlépá.
Áwn írúf énià b tí wn jìyà láb irú mi báyì á máa lò plp ákókó kí wn tó lé rí áwn óhún tí lgb wn mìràn ri gbà láié wáhálà jínà. Wn á máá é àékú kí wn lé rí óhún kán. Nìgbà ti wn bá sì má rí óhún nàà gbà tàn, gbógbó ày tió só m yió tí k fò l ná sájú.
Bibélì s pé, "iréti pip á máá mú kàn áár" Nígbàtí ó bá é àkíyèsí kùnrin tàbì óbirín tí mi yiì dà láàmú, gbógbó áwn tió kéré sí wn á máá rí kàn gbà kiákiá ájú wn. Nígbà tí áwn irú éniyàn báwnyì bá sá ipá tí wn, nà á há m wn, à lé kókó. Wn á máá sán óyé tí ó p jáì làtí rí oúnkòhún gbà, wn máa sábá j níkhìn làtí rí ìbùkún gbà, nikyìn làtí rí admissionù sí kljì, làtí é àéyrí nú ídànwò, làtí gbéyàwó tàbì l'k, làtí l'm pààpàà. Wn á tùn máa gbyìn pààpàà làtí làlùy.
Órúk àrín tí wn j à f lé yì pádà sí bùrdà tábì auntì ákyìn tábì ìgbyin. Ìbùkún wn kìì sábá dé br. Ítan Jákbù fí áwòràn írú éyí hàn wà, òhún tí mi ádábùkún ni dúró lé é sí áyié ní níyì. Bió tíl é pé áwn ìbùkún Jehofa mb lóri r, ó jiyà ìnírá ti kò é f'nú s lw Lábáni. Bi ò tí gbàdúrà lóni, Ólúwá yiò f àjàgà mi yì kúrò nínú áyié r, iw yiò wà wnú àyànm r l ni orúk Jésù.
Ní wíwò mì ádánidúró àtí àgbé àwn ìbùkún ni dè yì síwájú síí
Bíbórí mi ìdádúró àtí ágbé-bùkún dè yì j àigbd mójúkúrò lará r fún nitóripé áwn éniyàn wà ti á bí látí j Òlùdárí, Álágá ilé- p-ilú súgbn tí wn nsé Ábódè lásán nipás ípá mi yì. Áwn éniyàn mìràn y kí wn j Álábójútó gbógbó-gbó súgbn wn j òlùdárí àwn ilé isìn kéréjé-kéréjé ninú igbérikó lw báyì.
Áwn lómiràn ní àyànm àtí j professor sùgbn wn sé òlùk ilé-wé lásán báyì nitóripé mi ìdádúró àtí ágbébùkún dè yi wà lójú i nínú áyié wn. Áwn miràn tìl y ki wn j Billionaire, multimillionaire súgbn wn tr j lw báyì. plp éniyàn ní wn tí dí àgbésín plù talentì lórún lárá wn, wn mb ninú íbójì áwn òkú báyì.
p éniyàn ní ó wà nínú sáàrè ti wn kú plù áwn álá àtí ìràn ti wn kò rì mú nitóri mi ìdádúró àtí ágbébùkún dè yì. Áwn iwé ti ó lé yí ìgbé áyié dá pádà sí àrà lá mb ní íbójì áwn òkú, áwn irú éyi tí nikni kòi tì k rí, nipás mi ìdádúró àtí ágbébùkún áyié ni dè yì, ó tí í wn lw báyì.
Ákò lé sé àìrí áwn miràn tí wn ní àyànm àtí túné, wn lé yí óril-édé pádà sí gígá súgbn wn mb ninú sáàrè t'áwn tí álá wnyi, wn kò ní lé mú m láilái.
Iw tí ò kà iwé yì lw báyì, tá ló m bóyá ibi ti ó wà báyì kíì é ibi ti óy fún ?
Ó níilò àtí gbà gbógbó áwn kókó gbrùn-dínláádta ádùrà inú iwé yì.

Dettagli down

Generi Religioni e Spiritualità » Vita e pratica cristiana » Vita e pratica cristiana » Cristianesimo

Editore Tektime

Formato Ebook con Adobe DRM

Pubblicato 10/04/2021

Lingua Yoruba

EAN-13 9788835422518

0 recensioni dei lettori  media voto 0  su  5

Scrivi una recensione per "Ádúrà Egberun-Odin-Laadota Ti O Bori Emi Adaniduro Ati Afi Ibukun Eni Si Abamo"

Ádúrà Egberun-Odin-Laadota Ti O Bori Emi Adaniduro Ati Afi Ibukun Eni Si Abamo
 

Accedi o Registrati  per aggiungere una recensione

usa questo box per dare una valutazione all'articolo: leggi le linee guida
torna su Torna in cima